Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ.
2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ di Ọlọhun.
3- Ọrọ nipa isẹ ipepe anọbi Isa pẹlu isẹ ayanu rẹ, ati wipe Iru ẹlẹsin wo ni Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a].

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii