Awon Nkan Ti O leto Fun Musulumi Lati Maa Fi Se Iwosan

Oludanileko : Rafiu Adisa Bello

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Alaye ni ekunrere wa ninu ibanisoro yi lori awon nkan ti o leto fun Musulumi lati maa lo fun idena arun ati lati wa iwosan nigbati arun ba n se e. Bakannaa ni oro tun waye lori awon oogun ti o leto fun Musulumi lati lo ti o si so awon nkan ti esin se ni eewo fun Musumi.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii