Ojise Aanu
Awon oludanileko : Rafiu Adisa Bello - Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi
Sise atunyewo: Rafiu Adisa Bello
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata.
2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi san ibi.
3- Apejuwe lori aanu ti ojise Olohun ni fun awon eranko. Ikilo si waye lori fifi iya je awon eranko.
4- Apejuwe nipa aanu re si awon ewe tabi awon omode.
5- Apejuwe nipa aanu ojise Olohun si awon obinrin, oro si waye lori bi awon eniyan se maa nse abosi si won ni igba aimokan.
6- Awon apejuwe nipa iteriba ati iwapele ojise Olohun. Bi o ti se ni aanu awon omoleyin re ti awon naa si ni ife si i.
- 1
MP3 9.15 MB 2024-25-02
- 2
MP3 9.17 MB 2024-25-02
- 3
MP3 9.69 MB 2024-25-02
- 4
MP3 9.48 MB 2024-25-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: