Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah)

Oludanileko :

Sise atunyewo: Hamid Yusuf

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Eleyi ni iforowero laarin Ijo Ahmadiyyah ati Ijo Tadomun Muslimeen lori wipe se Annabi Isa- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ku si ori igi agbelebu ni tabi ko ku, se won gbe gun Sanmo lo ni tabi o wa ni ibikan lori ile aye yii.
2- Eleyi ni itesiwaju iforowero laarin igun mejeeji pelu awon eri olukuluku won lati le fi oro won mule.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii