Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi
Awon oludanileko : Rafiu Adisa Bello - Qomorudeen Yunus - Saeed Jumua
Sise atunyewo: Rafiu Adisa Bello - Saeed Jumua
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Waasi yi so nipa awon nkan kan, ninu won niyi: (1) Musulumi ni eni ti iwa daradara ti Islam pepe si ba han ni ara re. (2) Ninu ohun ti esin Islam pase re ni ki Musulumi maa se aponle gbogbo eniyan, eni ti o je Musulumi ati eni ti kiise Musulumi, ki o si maa dun won ninu.
- 2
Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi
MP4 60.13 MB 2024-17-10
- 3
Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi
MP3 13.06 MB 2024-17-10
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: