Ẹkọ nipa Apejẹ igbeyawo (Walimatu-Nikah)

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Idanilẹkọ yi sọ nipa idajọ ki eniyan se ounjẹ lati fi ko awọn eniyan lẹnu jọ ati bẹẹ bẹẹ lọ ninu awọn ẹkọ ti o rọ mọ apejẹ sibi igbeyawo (walimọtu- nikahi).

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii