Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii:
(i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo,
(ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii,
(iii) Majẹmu Rukiya,
(iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun,
(v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ, ọmọde ati lati fi wa iwosan.
- 1
Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo
MP3 27.1 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: