Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Description
1- Alaye ni ekunrere lori eto ise egbe alajeseku ni ilana ti Islam, ati alaye nipa aburu ti o nbe nibi owo-ele (Riba), eri re lati inu Alukuraani mimo ati Oro Ojise Olohun.
2-Alaye ni afikun lori awon okowo ti Islam gbe kale ti a le maa lo ninu egbe alajeseku gege bii: Musharakah, Mudarabah, Murabahah ati bee bee lo.
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii
- 1
- 2
Follow us: