• PDF

  Idanileko yii so nipa ohun ti a npe ni akaso ododo tabi wiwa ategun si odo Olohun eyi ti esin Islam pawa lase re. Oro die waye nipa awon eri lori bi a tise nwa ategun ati die ninu asise ti apakan ninu awon Musulumi maa nse

 • PDF

  Akosile yi da lori bi eniyan kan se le ri anabi wa Muhammad- ki ike ati ola Olohun maa ba a- ti yoo si mo wipe anabi gan an ni oun ri, bakannaa o se alaye bi o se je wipe awon eniyan kan maa n ri Esu [Shatani] ti won yoo si lero wipe anabi ni ti o si je wipe Esu ko ni agbara lati gbe aworan anabi wa Muhammad wo.

 • Ojise Aanu Yoruba

  MP3

  Oludanileko : Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

  1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata. 2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi san ibi. 3- Apejuwe lori aanu ti ojise Olohun ni fun awon eranko. Ikilo si waye lori fifi iya je awon eranko. 4- Apejuwe nipa aanu re si awon ewe tabi awon omode. 5- Apejuwe nipa aanu ojise Olohun si awon obinrin, oro si waye lori bi awon eniyan se maa nse abosi si won ni igba aimokan. 6- Awon apejuwe nipa iteriba ati iwapele ojise Olohun. Bi o ti se ni aanu awon omoleyin re ti awon naa si ni ife si i.

Irori re je wa logun