Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀

معلومات المواد باللغة العربية

Àwọn shii'a

Onka awon ohun amulo: 4

  • Yoruba

    YOUTUBE

    Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

    Diẹ nipa ete awọn Ijọ Shia fun awa Musulumi ti a wa lori Sunna Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a].

  • Yoruba

    YOUTUBE

    Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

    Alaye ni ẹkunrẹrẹ nipa adiọkan awọn Ijọ Shia: Adiọkan wọn nipa awọn Saabe Ojise Ọlọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], adiọkan wọn si Alukuraani ati bẹẹbẹẹ lọ.

  • Yoruba

    YOUTUBE

    Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello

    Alaye nipa bi Ijọ Shia se bẹrẹ pẹlu itọkasi wipe Yahuudi ni ẹni ti o pilẹ Ijọ Shia.

  • Yoruba

    MP3

    Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

    1- Alaye nipa awọn ijọ ti njẹ Shii’ah ati wipe ki ni adisọkan wọn nipa Ọlọhun ati si Alukuraani 2- Igbagbọ ijọ Shii’ah si awọn Sahabe ati ipo ti wọn gbe awọn asiwaju wọn si 3- Alaye diẹ ninu awọn adisọkan wọn gẹgẹ bii:- Tukyah, Muta’h. Ti oludanilẹkọ si tun jẹ ki a mọ adisọkan si ijọ Ahalu sunnah wal jamaa’ah