IslamHouse.com Gates

Àwọn èdè IslamHouse

Ibi ìkówèésí ọ̀fẹ́ tí ó jẹ́ ti da'wah ti a le ka, ti a le tẹ́tí gbọ́, ti a lè wò, pẹ̀lú èdè tí ó lé ní ọgọ́rùn-ún

Dán an wò nsinyii

Kuraani

Kíké Kuraani pẹ̀lú ohùn dídùn láti ẹnu àwọn gbajúgbajà àwọn oluka Kuraani

Dán an wò nsinyii

Igi pípín sí ìsọ̀rí ni ibamu si àkòrí

Fífi igi pín nǹkan sí ìsọ̀rí ni ìbámu sí àkòrí fún gbogbo àkóónú ibi ìkówèésí IslamHouse

Dán an wò nsinyii

Mọ̀ nípa Islam

Ọgọ́rọ̀ọ̀rún nínú àwọn iṣẹ́ ti ipepe pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èdè, èyí tí o nii ṣe pẹ̀lú bi èèyàn ṣe lè mọ nípa Isilaamu.

Dán an wò nsinyii

Muhammad ojiṣẹ Ọlọhun ni

Oju ewe ti o tobi julọ ti o sọ nipa Anabi awọn musulumi - Muhammad (Ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a) - pẹlu awọn ede gbogbo aye

Dán an wò nsinyii

Lati gba Islam bayii

Fun awọn ti wọn fẹ gba Isilaamu nísinsìnyí… Wọn le kàn si ọkan ninu awọn ti wọn n ṣàlàyé nipa Isilaamu pẹ̀lú awọn ede ti o pọ

Dán an wò nsinyii

Àwọn atẹjade ti a ti pèsè kalẹ fun titẹ jade

Awọn tira ti a farabalẹ ṣẹ̀sà pẹlu ọpọlọpọ èdè, a n damọran titẹ ẹ jade.

Dán an wò nsinyii

IslamHouse.com services

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ti i-meeli

Forúkọ silẹ nibi itolẹsẹẹsẹ awọn imeeli yii ki awọn nǹkan titun ti a gbé jáde ninu awọn ede kan lè dé ọdọ rẹ.

Dán an wò nsinyii

Eto iṣẹ balaag

Pe awọn ẹlomiran sinu ẹsin Isilaamu pẹlu lilo imeeli abi awọn ìkànnì àjọlò.

Dán an wò nsinyii

Eto iṣẹ tọrẹnti

Gba gbogbo àwọn akosinu èdè kan pàtó tabi alubọọmu kíké Kuraani tabi ọ̀wọ́ àwọn àtẹ́tísí pẹ̀lú títẹ bọ́tìnì ẹyọkan

Dán an wò nsinyii