عرض المواد باللغة الأصلية

أعلام وشخصيات

عدد العناصر: 27

  • يوربا

    مؤلف, عدد العناصر : 3

    Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ati oludari ile eko aladani Inayatullahi International Academy ni ilu Iwo. Won je okan ninu awon onimimo ni ilana sunna, won si ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ati itoju awon omo Musulumi.

  • يوربا

    مؤلف, مُراجع, عدد العناصر : 2

    O je akekojade ni ile eko giga ti o wa ni ilu Niger (Islamic University), o si tun ntesiwaju ni ile eko giga ni ilu Riyadh (King Saud)

  • يوربا

    مؤلف, عدد العناصر : 2

    Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ile eko nipa kika ati hiha Alukurani Alaponle. Won ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ni ilana awon oni sunna, won si ni oripa nibi itoju ati akolekan awon omo Musulumi.

  • يوربا

    مؤلف, عدد العناصر : 1

    Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina. Won si te siwaju fun eko onipogiga (Masters) ni ilu Nigeria. Won je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. Won si je eni ti o ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun.

  • يوربا

    مؤلف, عدد العناصر : 1

    O je akekojade ni ile eko giga Al-azhar University, o si tesiwaju fun eko onipokeji ni (International Islamic University) ni ilu Malasia. O je eni ti o ni igbiyanju ni ori ipepe si oju ona Olohun ni ilana sunna.

  • يوربا

    مؤلف, عدد العناصر : 1

    O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o tun ko eko onipokeji ni ile eko giga University of Ilorin. O je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni liana sunna, o si ni igbiyanju lori oro esin.

  • يوربا

    مؤلف, عدد العناصر : 1

    O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o si ni igbiyanju lori ipepe si esin ni ilana awon oni sunna.