Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ile eko nipa kika ati hiha Alukurani Alaponle. Won ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ni ilana awon oni sunna, won si ni oripa nibi itoju ati akolekan awon omo Musulumi.
Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina. Won si te siwaju fun eko onipogiga (Masters) ni ilu Nigeria. Won je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. Won si je eni ti o ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun.
O je akekojade ni ile eko giga Al-azhar University, o si tesiwaju fun eko onipokeji ni (International Islamic University) ni ilu Malasia. O je eni ti o ni igbiyanju ni ori ipepe si oju ona Olohun ni ilana sunna.
O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o tun ko eko onipokeji ni ile eko giga University of Ilorin. O je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni liana sunna, o si ni igbiyanju lori oro esin.