Onkọwe,Eni ti o se atunyewo,Eni ti o se ogbifo,Onka awon ohun amulo : 20
O je omo akekojade ni ile eko giga Lagos State Polytechnic ni ilu Eko. O si je eniti o feran lati maa pepe si oju ona Islam. O je Muslumi tooto ni oju ona ti sunna.
Eni ti o se ogbifo,Onkọwe,Onka awon ohun amulo : 46
Sheikh Sharafudeen Gbadebo: O je okan ninu awon olukekojade ni ile eko Islamic University ni ilu Madina, O ni igbiyanju lori titu awon iwe esin si ede Yoruba nigbati o n keko ni ilu Madina. O si je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni ilana Sunna ni ile Yoruba.
Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ati oludari ile eko aladani Inayatullahi International Academy ni ilu Iwo. Won je okan ninu awon onimimo ni ilana sunna, won si ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ati itoju awon omo Musulumi.