Description

Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii:
1. Titẹle asẹ rẹ.
2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo.
3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi.
4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati didaabo bo Sunnah rẹ.

Irori re je wa logun