- Igi pípín sí ìsọ̀rí
- Al-Quraani Alaponle
- Sunna
- Ìmọ̀ Akiida
- Ìmọ̀ Taohiid àti ìpín rẹ
- Ìjọsìn ati ìran rẹ̀
- Islam
- Ìgbàgbọ́ ati awọn origun rẹ̀
- Ìgbàgbọ́ ninu Ọlọhun
- Ìgbàgbọ́ nínú àwọn malaika
- Ìgbàgbọ́ nínú àwọn tira
- Ìgbàgbọ́ nínú àwọn ojiṣẹ àti àwọn ìròyìn wọn
- Ìgbàgbọ́ ninu Anọbi Isa ki àlàáfíà maa ba a
- Ìtàn àwọn Anọbi
- Àwọn àlá
- Muhammad ojiṣẹ Ọlọhun ni
- Ìgbàgbọ́ nínú Muhammad ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Àwọn iwọ̀ Anọbi ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Àwọn ẹ̀rí ìjẹ́ anọbi Muhammad ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Àwọn ìrújú nípa Muhammad ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Ohun ọ̀ṣọ́ ile ati ohun èlò àti ohun ìjà rẹ ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a.
- Àwọn ogun ti ó jà ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Oúnjẹ rẹ, nǹkan mimu rẹ, oorun rẹ, kí ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Àwọn ijẹrii déédéé nípa Anọbi Muhammad ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Ikẹ ati ọla maa ba ojiṣẹ Ọlọhun
- Àwọn ọrọ oríṣiríṣi ti o jẹ mọ́ Anọbi Islam
- Àwọn ọmọ-ọdọ ati awọn ẹrú rẹ, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Hijira rẹ ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa bá a
- Awọn ìwà ati ìròyìn Anabi
- Àwọn ọrọ nípa ìgbàgbọ́
- Ìgbàgbọ́ nínú kádàrá
- Ìgbàgbọ́ nínú ọjọ́ ìkẹyìn
- Ṣíṣe dáadáa
- Ṣíṣe aigbagbọ
- Ìwà munaafiki
- Ẹbọ àti ewu rẹ̀
- Àwọn adadaalẹ ati ìran wọn àti àpèjúwe wọn
- Àwọn sàábé ati awọn aráalé anọbi Muhammad
- Wíwá àtẹ̀gùn
- Jijẹ wòlíì ati awọn iṣẹ ìyanu àwọn wòlíì
- Idán ati pípa ọwọ́ dà
- Àwọn alujannu
- Ìsòtítọ́ àti ìbọ́pá-bọ́sẹ̀ ati awọn ìdájọ́ rẹ.
- Àwọn ahlus sunna wal jamaa'at
- Àwọn ẹ̀sìn
- Àwọn ẹgbẹ́
- Àwọn ẹgbẹ́ inú Islam
- Àwọn ọ̀nà ìròrí ayé òde òní
- Àwọn ipepe ti àtúnṣe
- Àwọn tira akiida
- Agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Imọra ati awọn idajọ rẹ
- Irun
- Ìdájọ́ irun
- Irun pipe
- Àwọn àkókò irun wákàtí márùn-ún
- àwọn májẹ̀mú irun
- Àwọn origun irun
- Àwọn ọranyan irun
- Àwọn sunna irun
- Bi a ṣe n kirun
- Àwọn azkaar ẹyin irun wákàtí márùn-ún
- Àwọn nǹkan ti n ba irun jẹ
- Irun janmọọn
- Iforikanlẹ ìgbàgbé
- Iforikanlẹ kíké Kuraani
- Iforikanlẹ ọpẹ
- Àwọn idajọ ṣíṣe imaamu
- Irun àwọn ti wọn ni àwíjàre
- Irun Jímọ̀
- Irun àkígbọrẹ
- Òkú
- Sàká
- Aawẹ
- Hajj ati Umra
- Àwọn idajọ mọṣalaasi abeewọ
- Àwọn ààyè ti a ti n gbé áràmí
- Gbígbé áràmí
- Àwọn ìran iṣẹ́ hajj
- Bi a ṣe n ṣe umura
- Bi a ṣe n ṣe hajj
- Jíjẹ́ kí ẹnikan bá ẹlòmíràn ṣe iṣẹ Hajj.
- Ìdájọ́ ki àràfá bọ́ mọ́ èèyàn lọ́wọ́ ati ki ìdènà kọdí èèyàn lati pé iṣẹ́ hajj tabi umura
- Àwọn idajọ mọṣalaasi Anọbi
- Ẹran adaaya
- Ẹran iléyá
- Kini o n kan lẹ́yìn hajj
- Biba ara ẹni lo
- Kátàkárà
- Àwọn Kátàkárà ti a ṣe ni ẹtọ
- Àwọn Kátàkárà ti a ṣe ni eewọ
- Rìbá
- Yíyálówó
- Fífi nǹkan dógò
- Ìfọwọ́sọ̀yà ati ìṣe onídùúró
- Dida nnkan papọ
- Yíyáni-ní-nnkan pẹ̀lú gbigba nǹkan rọ́pò.
- Tẹ́tẹ́ títa
- Nǹkan ti a rí he àti ọmọ tí a rí he
- Waqfu
- Ẹ̀bùn
- Ọrẹ àtinúwá ní ojú ayé ẹni tí wọ́n máa ṣe àmúlò rẹ lẹ́yìn tí èèyàn bá kú
- Àwọn ọrọ ti o jẹ mọ́ owó ti òde òní
- Ibara-ẹni-lo-papọ ti o jẹ ti owó
- Ìmọ̀ nípa ogún pípín
- Kátàkárà
- Ìbúra àti ìlérí
- Ẹbí
- Ìgbéyàwó
- Kíkọ obìnrin
- Gbígba obìnrin tí a kọ̀ padà
- Kí ìyàwó kọ ọkọ silẹ
- Bibura pe eeyan ko nii sunmọ ìyàwó rẹ̀
- Fifi ẹ̀yìn ìyàwó ẹni wé ti ìyá ẹni
- Kí ọkọ àti ìyàwó jọ gbé ara wọn ṣẹ́ èpè
- Àsìkò tí obìnrin ti òun àti ọkọ rẹ pínyà fi máa kóra ró
- Fífún lọ́yàn
- Títọ́jú
- Ìnáwó
- Aṣọ àti ọ̀ṣọ́
- Fàájì àti àríyá
- Àwùjọ Musulumi
- Ọrọ nipa àwọn obìnrin
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọmọdé
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọ̀dọ́
- Ìwòsàn àti lílo oògùn àti rukiya ti o bá sheria mu
- Àwọn oúnjẹ ati awọn nǹkan mímu
- Dídá ọ̀ràn
- Àwọn ìjìyà nínú ẹsin
- Ìdájọ́
- Jijagun ẹ̀sìn
- Agbọye awọn àlámọ̀rí tuntun ti o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣẹlẹ̀ ti o n bukata si idajọ ẹsin
- Agbọye ẹ̀sìn àwọn to kéré jù
- Àwọn idajọ Mùsùlùmí tuntun
- Òṣèlú ti shẹria
- Awọn ojú ìwòye nípa agbọye ẹ̀sìn
- Fatawa
- Awọn ipilẹ (ìlànà) agbọye ẹsin.
- Àwọn tira agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré ti o jẹ ti ìmọ̀.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré ti o n ṣàlàyé ìtumọ̀ Kuraani.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nipa kika Kuraani dáadáa ati awọn ọna ti a le gba ka Kuraani.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nípa adisọkan.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nípa Sunna
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nipa ìmọ̀ Nahw
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nípa ìmọ̀ Usuulul Fiqh
- Àwọn ọrọ ṣókí nínú tira kékeré nípa ìmọ̀ Fiqh
- Àwọn ọrọ ṣókí nínú tira kékeré ati awọn tira alátẹ̀tísí
- Awọn iwa rere
- Ìmọ̀
- Imọkanga
- Àwọn ọlá ti n bẹ fún ìjọsìn
- Ọlá ti n bẹ fún ìwà
- Ọlá ti n bẹ fún dída ẹbí pọ̀ ati ṣíṣe dáadáa sí àwọn òbí méjèèjì
- Ọlá ti n bẹ fún Kuraani
- Ọlá ti n bẹ fún àwọn sàábé
- Àwọn ẹ̀kọ́
- Awọn ọrọ ti maa n jẹ ki ọkàn ó rọ̀ àti àwọn wáàsí.
- Àwọn adua
- Pipepe si ojú ọ̀nà tí Ọlọhun
- Àwọn iṣẹ́ aṣegbọrẹ
- Pipepe sínú Islam
- Ìmúnimọ nǹkan ti wọn n pe ni Islam
- Bùkátà àwọn èèyàn si Islam
- Àwọn dáadáa ati ọla ti n bẹ fún Islam
- Iwọntunwọnsi ati idurotọ ati igbesumọmi ninu Isilaamu.
- Kikari ẹsin Islam
- Iwọ̀ ọmọniyan ninu Islam
- Iwọ̀ ẹranko ninu Islam
- Pípe àwọn ti kii ṣe Musulumi
- Pipaṣẹ dáadáa ati kikọ kuro nibi ibajẹ.
- Báwo ni waa ṣe wọ inú Islam
- Kilode ti wọn fi gba Islam? Ìtàn àwọn Musulumi tuntun
- Àwọn ìrújú nípa Islam
- Àwọn ijẹrii déédéé nípa Islam
- Ìtàn ìgbésí ayé àwọn olupepe si ti Ọlọhun
- Ipò ti pipepe si ti Ọlọhun wa
- Issues That Muslims Need to Know
- Ede Larubawa
- Ìtàn
- Ọlaju Islam
- Awọn iṣẹlẹ igbadegba.
- Ipò ti àwọn Musulumi wa ni òní
- Ẹkọ ati awọn ile-ẹkọ
- Igberoyinjade ati ikọroyin silẹ
- Awọn iwe iroyin ati awọn ìpàdé àpérò ti o jẹ ti imọ.
- Ibaraẹnisọrọ ati Intanẹẹti.
- Ọlaju Islam
- Kíkọ́ nipa èdè, àṣà ati ìṣe àwọn Lárúbáwá ati awọn ti wọn kọ́ nípa wọn
- Àwọn ìmọ̀ lọdọ àwọn Mùsùlùmí
- Àwọn ètò Islam
- Awọn ìdíje ti ìkànnì náà
- Àwọn ètò ati ohun èlò orí kọnputa lorisirisi
- Àwọn líǹkì
- Ìdarí
- Curriculums
- Àwọn khutuba orí minbari
Fonran ohun
Onka awon ohun amulo: 147
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ ti o se alaye siso gbekude mọ ara, gbere sinsin ati nkan miran ti o fi ara pẹẹ lara awọn ohun ti o jẹ mọ ẹbọ sise.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ sise Aimoore si Ọlọhun (Allah) ati awọn ọna ti o pin si pẹlu iyatọ ti o n bẹ laarin kufuru Nla ati kufuru keekeeke.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ igbagbọ si kadara pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah. Lẹyin naa idahun waye si ibeere yi: “ Njẹ a le fi kadara se ikẹwọ fun ẹsẹ dida bii?”
- Yoruba Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye awọn ọna ti o tọ, ti Musulumi fi le maa se atẹgun lọ si ọdọ Ọlọhun Allah
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye itumọ nini igbagbọ nipa ọjọ Ikẹhin pẹlu ẹri rẹ lati inu Shẹriah
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Ninu idanilẹkọ yii: (i) Itumọ nini igbagbọ si awọn Ojisẹ Ọlọhun pẹlu ẹri rẹ lati Shẹriah, (ii) Pataki awọn Ojisẹ Ọlọhun ati bukaata wa si wọn.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ gbigba awọn tira Ọlọhun gbọ ati ojupọnna ti o yẹ ki a fi gba wọn gbọ pẹlu awọn ẹkọ ti a le kọ nibi gbigba awọn tira Ọlọhun gbọ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Alaye iru ẹni ti awọn Malaikaa se, ati wipe ojupọnna wo ni o yẹ ki a fi gba wọn gbọ 2- Awọn ẹkọ ti a le kọ nibi gbigba awọn Malaika gbọ
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ Mimu Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Isẹ Awa Ẹda ( Taohiidul-Uluuhiyyah ) pẹlu alaye wipe Taohiid yii ni o maa nda ija silẹ laarin awọn ojisẹ ati awọn ijọ wọn
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ Mimu Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Ise Rẹ (Taohiidur-Rubuubiyyah) ati awọn ẹri lori rẹ, pẹlu awọn koko alaye ọrọ ti rọ mọ ọn
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ nini igbagbọ si Ọlọhun Allah pẹlu awọn ohun ti njẹri si bibẹ Ọlọhun naa.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Ọrọ nipa awọn ipilẹ adiọkan Musulumi, pataki mimọ amọdaju rẹ, lilo lati fi se isẹ se ati ipepe lọ sibẹ
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ adiọkan Musulumi ati awọn ẹsan ti n bẹ fun adiọkan ti o ni alaafia ati eyi ti ko ni alaafia
- Yoruba Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Awọn iroyin ti eniyan fi le moribọ kuro ninu ofo aye, awọn iroyin naa ni: (i) Igbagbọ to peye ninu Ọlọhun Allah, (ii) sise isẹ tọ igbagbọ, (iii) igbara ẹni ni iyanju sise daadaa, (iv) igbara ẹni ni iyanju sise suuru.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Alaye nipa aayah Alukuraani ti o wa lori asalaatu sise fun Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], pataki asalaatu ati wipe bawo ni o se yẹ ki a maa se. 2- Pataki sise asalaatu fun Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọjọ Jimọh ati anfaani ti o wa nibẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
1- Alaye nipa awọn ijọ ti njẹ Shii’ah ati wipe ki ni adisọkan wọn nipa Ọlọhun ati si Alukuraani 2- Igbagbọ ijọ Shii’ah si awọn Sahabe ati ipo ti wọn gbe awọn asiwaju wọn si 3- Alaye diẹ ninu awọn adisọkan wọn gẹgẹ bii:- Tukyah, Muta’h. Ti oludanilẹkọ si tun jẹ ki a mọ adisọkan si ijọ Ahalu sunnah wal jamaa’ah
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Itumọ ijọsin, awọn majẹmu ati erenjẹ ti o wa nibi sise e, ati wipe nitori kini a se nse ijọsin.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii: 1. Titẹle asẹ rẹ. 2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo. 3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi. 4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati didaabo bo Sunnah rẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Koko ibanisọrọ yii ni: (i) Itumọ atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun (ii) Awọn ọna ti a ngba se atẹgun lati wa oore ni ọdọ Ọlọhun. (iii) Awọn gbolohun ti o lẹtọ ti Musulumi fi le se atẹgun lọ si ọdọ Ọlọhun.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.
Follow us: