Sise asalaatu fun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a]

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Alaye nipa aayah Alukuraani ti o wa lori asalaatu sise fun Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], pataki asalaatu ati wipe bawo ni o se yẹ ki a maa se.
2- Pataki sise asalaatu fun Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọjọ Jimọh ati anfaani ti o wa nibẹ.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii