Sise asalaatu fun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a]
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Alaye nipa aayah Alukuraani ti o wa lori asalaatu sise fun Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], pataki asalaatu ati wipe bawo ni o se yẹ ki a maa se.
2- Pataki sise asalaatu fun Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọjọ Jimọh ati anfaani ti o wa nibẹ.
- 1
Sise asalaatu fun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] -1/ 2
MP3 23.4 MB 2019-05-02
- 2
Sise asalaatu fun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] - 2/ 2
MP3 20.7 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: