- Igi pípín sí ìsọ̀rí
- Al-Quraani Alaponle
- Sunna
- Ìmọ̀ Akiida
- Ìmọ̀ Taohiid àti ìpín rẹ
- Ìjọsìn ati ìran rẹ̀
- Islam
- Ìgbàgbọ́ ati awọn origun rẹ̀
- Àwọn ọrọ nípa ìgbàgbọ́
- Ṣíṣe dáadáa
- Ṣíṣe aigbagbọ
- Ìwà munaafiki
- Ẹbọ àti ewu rẹ̀
- Àwọn adadaalẹ ati ìran wọn àti àpèjúwe wọn
- Àwọn sàábé ati awọn aráalé anọbi Muhammad
- Wíwá àtẹ̀gùn
- Jijẹ wòlíì ati awọn iṣẹ ìyanu àwọn wòlíì
- Àwọn alujannu
- Ìsòtítọ́ àti ìbọ́pá-bọ́sẹ̀ ati awọn ìdájọ́ rẹ.
- Àwọn ahlus sunna wal jamaa'at
- Àwọn ẹ̀sìn
- Àwọn ẹgbẹ́
- Àwọn ẹgbẹ́ inú Islam
- Àwọn ọ̀nà ìròrí ayé òde òní
- Agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Imọra ati awọn idajọ rẹ
- Irun
- Òkú
- Sàká
- Aawẹ
- Hajj ati Umra
- Àwọn idajọ khutuba Jímọ̀
- Irun aláìsàn
- Irun arìnrìn-àjò
- Irun ìpayà
- Biba ara ẹni lo
- Ìbúra àti ìlérí
- Ẹbí
- Ìgbéyàwó
- Kíkọ obìnrin
- Kíkọ obìnrin tí ó bá sunna mu ati Kíkọ obìnrin ti ko ba sunna mu
- Kíkọ obìnrin ti a lè gbà padà ati èyí tí a o lè gbà padà
- Àsìkò tí obìnrin ti òun àti ọkọ rẹ pínyà fi máa kóra ró
- Kí ọkọ àti ìyàwó jọ gbé ara wọn ṣẹ́ èpè
- Fifi ẹ̀yìn ìyàwó ẹni wé ti ìyá ẹni
- Bibura pe eeyan ko nii sunmọ ìyàwó rẹ̀
- Kí ìyàwó kọ ọkọ silẹ
- Gbígba obìnrin tí a kọ̀ padà
- Fífún lọ́yàn
- Títọ́jú
- Ìnáwó
- Aṣọ àti ọ̀ṣọ́
- Fàájì àti àríyá
- Àwùjọ Musulumi
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọ̀dọ́
- Ọrọ nipa àwọn obìnrin
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọmọdé
- Ìwòsàn àti lílo oògùn àti rukiya ti o bá sheria mu
- Àwọn oúnjẹ ati awọn nǹkan mímu
- Dídá ọ̀ràn
- Ìdájọ́
- Jijagun ẹ̀sìn
- Agbọye awọn àlámọ̀rí tuntun ti o ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣẹlẹ̀ ti o n bukata si idajọ ẹsin
- Agbọye ẹ̀sìn àwọn to kéré jù
- Àwọn idajọ Mùsùlùmí tuntun
- Òṣèlú ti shẹria
- Awọn ojú ìwòye nípa agbọye ẹ̀sìn
- Fatawa
- Awọn ipilẹ (ìlànà) agbọye ẹsin.
- Àwọn tira agbọye ẹsin
- Àwọn ìjọsìn
- Awọn iwa rere
- Ede Larubawa
- Pipepe si ojú ọ̀nà tí Ọlọhun
- Pipepe sínú Islam
- Ohun ti o jẹ dandan fun Musulumi
- Awọn ọrọ ti maa n jẹ ki ọkàn ó rọ̀ àti àwọn wáàsí.
- Pipaṣẹ dáadáa ati kikọ kuro nibi ibajẹ.
- Ipò ti pipepe si ti Ọlọhun wa
- Ìtàn
- Ọlaju Islam
- Awọn iṣẹlẹ igbadegba.
- Ipò ti àwọn Musulumi wa ni òní
- Ẹkọ ati awọn ile-ẹkọ
- Igberoyinjade ati ikọroyin silẹ
- Awọn iwe iroyin ati awọn ìpàdé àpérò ti o jẹ ti imọ.
- Ibaraẹnisọrọ ati Intanẹẹti.
- Àwọn ìmọ̀ lọdọ àwọn Mùsùlùmí
- Àwọn ètò Islam
- Awọn ìdíje ti ìkànnì náà
- Àwọn ètò ati ohun èlò orí kọnputa lorisirisi
- Àwọn líǹkì
- Ìdarí
- Àwọn khutuba orí minbari
- Academic lessons
- General Public of Muslims
- Àwọn tira akiida
- Ìmọ̀
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré ti o jẹ ti ìmọ̀.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré ti o n ṣàlàyé ìtumọ̀ Kuraani.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nipa kika Kuraani dáadáa ati awọn ọna ti a le gba ka Kuraani.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nípa adisọkan.
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nípa Sunna
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nipa ìmọ̀ Nahw
- Awọn ọ̀rọ̀ ṣókí nínú tira kékeré nípa ìmọ̀ Usuulul Fiqh
- Àwọn ọrọ ṣókí nínú tira kékeré nípa ìmọ̀ Fiqh
- Àwọn ọrọ ṣókí nínú tira kékeré ati awọn tira alátẹ̀tísí
- Seekers of Knowledge
- Seekers of Knowledge (Beginners)
Awọn iwa rere
Onka awon ohun amulo: 61
- Yoruba Kiko iwe : Sa’id Bn Ali Bn Wahf Al-Qahtaani
AWON ADUA TI WON JE AABO FUN MUSULUMI LATI INU AL-QUR’AANI ATI SUNNA
- Yoruba
Èyí, nínú ìran rẹ̀, ni àkọ́kọ́ àkànṣe iṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára, tó ní í ṣe pẹ̀lú ìmọ̀ ẹ̀rọ, èyí tó ní àkàkún pẹ̀lú ìlànà afaraṣe Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – àti àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́. Ó ń bá gbogbo èdè àgbáyé, èyí tó gbajúmọ̀ jùlọ sọ̀rọ̀ láti ipasẹ̀ àwọn àpilẹ̀kọ tí à ń kà, àwọn àwòrán àti àwọn ohùn tí a gbà sílẹ̀, pẹ̀lú ọlọ́kan-ò-jọ̀kan nínú àwọn nǹkan àrà-ọ̀tọ̀ tó pàtàkì.
- Yoruba Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Ọrọ nipa awọn okunfa aseju ninu ẹsin ati awọn ohun ti o le dẹkun tabi fi opin si sise aseju ninu ẹsin Islam.
- Yoruba Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Alaye ohun ti njẹ aseju ninu ẹsin, ipilẹ ati paapaa aseju ninu ẹsin ati awọn apejuwe rẹ.
- Yoruba Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Akọsilẹ ti o sọ nipa anfaani ti o n bẹ nibi adua fun Musulumi ododo ati bi o se jẹ ohun ti Ọlọhun fẹran lati ọdọ ẹru Rẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Awọn imọran fun gbogbo Musulumi lori bi igbiyanju si oju ọna ẹsin yoo se maa tẹsiwaju ni ohun ti wọn fi kadi eto nilẹ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Ọrọ waye ninu apa keji yii lori: (1) Iwọ ti o yẹ ki awa Musulumi maa pe fun awọn saabe Anabi. (2) Awọn ẹri ti o fi ẹsẹ mulẹ lori wipe ko si ede aiyede laarin awọn ara ile Anabi ati awọn Saabe yoku.
- Yoruba Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Awọn ohun ti o waye ninu apa yii: (1) Itumọ Saabe ninu ede larubawa ati wipe taani awọn Saabe gẹgẹ bi awọn onimimọ se se apejuwe wọn. (2) Ipo ati ọla ti nbẹ fun awọn Saabe pẹlu ẹri rẹ lati inu Sunna.
- Yoruba Oluko : Sa’id Bn Ali Bn Wahf Al-Qahtaani Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Diẹ ninu awọn iranti Ọlọhun ti o yẹ ki Musulumi o mọ ki o si maa se ni ojoojumọ lati inu iwe Husnul Muslim.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yii da lori alaye bi a se nse aluwala ati awọn ẹsan (ọla) ti o nbẹ fun aluwala sise, bakannaa ọrọ nipa awọn ohun ti o nsọ aluwala di ọranyan fun musulumi.
- Yoruba Sise ogbifo : Rafiu Adisa Bello Sise atunyewo : Abdur Rasheed Adeniyi Abdur Rahuf
Ibeere nipa itumo aseju ninu esin, awon onimimo se alaye ohun ti o n je aseju ninu esin won si mu apejuwe re wa pelu awon eri.
- Yoruba Oluko : Rafiu Adisa Bello
Oore ti o po pupo ni o wa nibi irun kiki fun Musulumi. Ohun ni ona ti o dara julo lati wa asunmo si odo Olohun, o si maa nse okunfa aforiji fun Musulumi, bakannaa ni o je oluranlowo fun erusin lati wo ogba idera (al-Jannah).
- Yoruba Oluko : Rafiu Adisa Bello
Akosile yi so nipa bi irun kiki ti se pataki to ninu esin Islam, ohun ni origun ti o lola julo leyin ijeri mejeeji, ohun naa si ni ise ti erusin maa n se ti o loore julo leyin won.
- Yoruba
- Yoruba
Mó ń gbé síwájú rẹ, ìrẹ ọmọ-ìyá mi nínú ẹ̀sìn Islām, tí ó ń ka ìwé yìí; àwọn ìlànà Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ láti ìgbà tí ó bá ti jí, títí di ìgbà tí yóò sùn, èyí tí a tò ní ìbámu sí àsìkò wọn, lẹ́yìn náà máa fi àwọn ìlànà Ànábì mìíràn tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́, èyí tí kò ní àsìkò kan pàtó, tẹ̀lé e.
- Yoruba Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Khutuba yii da lori pataki adua sise ati anfaani to wa nibi adua sise Itẹsiwaju alaye lori pataki adua sise
- Yoruba Oludanileko : Qomorudeen Yunus Sise atunyewo : Hamid Yusuf
[1] Asọtẹlẹ lati ọdọ Ọlọhun Allah ni sise daada si obi ẹni. [2] Alukuraani ati ẹgbawa hadisi sọ nipa pataki daada sise si awọn obi mejeeji. [3] Apẹẹrẹ oniran-nran daada ti eniyan le maa se si awọn obi rẹ. [4] Awọn ojuse ọmọ si obi pẹlu awọn apejuwe ifisisẹse rẹ lati ọdọ awọn sahabe Anọbi. [5] Awọn anfaani ti o wa nibi daada sise si awọn obi ẹni. Alaye nipa sise daada si awọn obi ẹni lẹyin ti wọn ti jade laye.
- Yoruba Oludanileko : Dhikrullah Shafihi Sise atunyewo : Rafiu Adisa Bello
Idanilẹkọ nipa awọn okunfa gbigba adua, ati wipe ẹniti o ba ni ifẹ si ilu rẹ gbọdọ maa se adua ki ilu naa dara.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yii da lori awọn ọna ti musulumi fi le wa isọ Ọlọhun ati aabo Rẹ gẹgẹ bii: Jijẹ eso dabidun ‘ajiwa, sise aluwala loore koore, mima ki irun Fajri ni jama’a, mima ki irun oru, ati bẹẹ bẹẹ lọ.
- Yoruba Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf
Idanilẹkọ yii sọ nipa awọn ẹsan ati pataki sise iranti Ọlọhun.