Àwọn Sunnah Ànábì Àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́

Kiko iwe :

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Mó ń gbé síwájú rẹ, ìrẹ ọmọ-ìyá mi nínú ẹ̀sìn Islām, tí ó ń ka ìwé yìí; àwọn ìlànà Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ láti ìgbà tí ó bá ti jí, títí di ìgbà tí yóò sùn, èyí tí a tò ní ìbámu sí àsìkò wọn, lẹ́yìn náà máa fi àwọn ìlànà Ànábì mìíràn tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́, èyí tí kò ní àsìkò kan pàtó, tẹ̀lé e.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii