Àwọn Sunnah Ànábì

SONAN fun Android

The application available in following stores

SONAN fun Apple

The application available in following stores

Onímọ̀ nípa ẹ̀rọ kọ̀ǹpútà :

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Èyí, nínú ìran rẹ̀, ni àkọ́kọ́ àkànṣe iṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára, tó ní í ṣe pẹ̀lú ìmọ̀ ẹ̀rọ, èyí tó ní àkàkún pẹ̀lú ìlànà afaraṣe Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – àti àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́. Ó ń bá gbogbo èdè àgbáyé, èyí tó gbajúmọ̀ jùlọ sọ̀rọ̀ láti ipasẹ̀ àwọn àpilẹ̀kọ tí à ń kà, àwọn àwòrán àti àwọn ohùn tí a gbà sílẹ̀, pẹ̀lú ọlọ́kan-ò-jọ̀kan nínú àwọn nǹkan àrà-ọ̀tọ̀ tó pàtàkì.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii

Asọkun ọrọ