Itumọ Suuratul-Asri ati diẹ ninu awọn Anfaani rẹ

Oludanileko :

Sise atunyewo: Hamid Yusuf

نبذة مختصرة

Awọn iroyin ti eniyan fi le moribọ kuro ninu ofo aye, awọn iroyin naa ni: (i) Igbagbọ to peye ninu Ọlọhun Allah, (ii) sise isẹ tọ igbagbọ, (iii) igbara ẹni ni iyanju sise daadaa, (iv) igbara ẹni ni iyanju sise suuru.

التصانيف العلمية:

Irori re je wa logun