Alaye nipa Ijọ Shii’ah

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Alaye nipa awọn ijọ ti njẹ Shii’ah ati wipe ki ni adisọkan wọn nipa Ọlọhun ati si Alukuraani
2- Igbagbọ ijọ Shii’ah si awọn Sahabe ati ipo ti wọn gbe awọn asiwaju wọn si
3- Alaye diẹ ninu awọn adisọkan wọn gẹgẹ bii:- Tukyah, Muta’h. Ti oludanilẹkọ si tun jẹ ki a mọ adisọkan si ijọ Ahalu sunnah wal jamaa’ah

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii