Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye Sisọkalẹ Anọbi Isa [ Ọla Ọlọhun ki o maa ba a ]

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Apejuwe bi Anabi Isa [Ọla Ọlọhun ki o maa ba a] yoo se sọkalẹ nigbati aye ba n lọ si opin pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani, ẹgbawa hadisi ati ọrọ awọn aafa onimimọ.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii