Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna

Oludanileko : Rafiu Adisa Bello

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti a fi maa nmo adadaale nitori awon iruju ti o wa fun awon Musulumi kan lori re.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii

Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: