Oludanileko : Abdul-jeleel Alagufon

Sise atunyewo: Hamid Yusuf

Description

Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi:
(1) Itumo Ayanmo.
(2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo.
(3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise.
(4) Awon ipele Ayanmo.
(5) Ninu awon idi ti Olohun fi se Ayanmo ni ohun asiri ati ipamo.

Irori re je wa logun