Idanileko yi je alaye nipa hadiisi eleekefa ninu tira “Umdatul Ahkaam”. Oludanileko so nipa egbin aja ati awon idajo ti o ro mo o, o si tun so nipa awon agbegbe ti esin ti gba awa Musulumi laaye lati se anfaani lara aja gege bii fifi so ile ati beebee lo
Ibanisoro yi da lori Pataki odun mejeeji ninu Islam: odun itunu aawe ati odun ileya, olubanisoro si so bi ojise Olohun se gba awa Musulumi ni iyanju lori kiko awon ara ile wa lo si aaye ikirun ni ojo odun. Ni afikun, o tun so die nipa idajo Janaba ati eje nkan osu obinrin.