-
Abdur-rosheed Ballo Oluajo "Onka awon ohun amulo : 1"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o tun ko eko onipokeji ni ile eko giga University of Ilorin. O je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni liana sunna, o si ni igbiyanju lori oro esin.