-
Abdullahi Sayuuti "Onka awon ohun amulo : 4"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :Sheikh Abdullahi Sayuuti: Akekojade ni ile eko giga Bayero University ni ilu Kano, won si tun keko Diploma ni ile eko giga Islamic University, Republic of Niger. Bakannaa won ko eko ni odo awon onimimo ni ile Nigeria lori imo Tefsiri, Hadiisi ati imo agboye esin. Won je olupepe si oju ona esin ni ilana ti awon oni sunna.