-
Sirajudeen Bilal Al-asrau "Onka awon ohun amulo : 3"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ati oludari ile eko aladani Inayatullahi International Academy ni ilu Iwo. Won je okan ninu awon onimimo ni ilana sunna, won si ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ati itoju awon omo Musulumi.