Onka awon ohun amulo: 81
26 / 1 / 1436 , 19/11/2014
Alaye lori awọn ekọ ati awọn ohun ti o je dandan fun musulumi lati se nigbati o ba fẹ se igbansẹ, ọrọ si tun waye lori awọn aaye ti a kọ fun ni lati se igbansẹ si.