• Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 7

    Sheikh Abdul-jeleel Alagufon: Won keko jade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je olupepe si oju ona Olohun ni ilana ti Sunna ni ile Yoruba. Won je okan lara awon Jama'tu Tadoomunul Muslimeen.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 3

    Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je osise lowolowo ni ile eko giga ti ijoba ni ilu Ilorin. Won je olupepe si oju ona Olohun ni ilana sunna.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 1

    Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina. Won si te siwaju fun eko onipogiga (Masters) ni ilu Nigeria. Won je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. Won si je eni ti o ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 2

    Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ile eko nipa kika ati hiha Alukurani Alaponle. Won ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ni ilana awon oni sunna, won si ni oripa nibi itoju ati akolekan awon omo Musulumi.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 4

    Sheikh Abdullahi Sayuuti: Akekojade ni ile eko giga Bayero University ni ilu Kano, won si tun keko Diploma ni ile eko giga Islamic University, Republic of Niger. Bakannaa won ko eko ni odo awon onimimo ni ile Nigeria lori imo Tefsiri, Hadiisi ati imo agboye esin. Won je olupepe si oju ona esin ni ilana ti awon oni sunna.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 81

    Ustaz Abdur Rahman Muhammadul Awwal: O je akekojade ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o si tun te siwaju fun eko onipokeji ni University of Ilorin, o nse eto eko dokita re lowo bayi ni ile eko giga naa. O ni igbiyanju lori ise ipepe si oju ona Olohun ni ilana awon oni sunna.

  • Yoruba

    Onkọwe, Eni ti o se atunyewo, Onka awon ohun amulo : 2

    O je akekojade ni ile eko giga ti o wa ni ilu Niger (Islamic University), o si tun ntesiwaju ni ile eko giga ni ilu Riyadh (King Saud)

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 3

    O je akekojade ni Ile-eko giga "Imam" eka to Mauritania, O si je olupepe si oju ona Olohun ni ilana sunna

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 1

    O je akekojade ni ile eko giga Al-azhar University, o si tesiwaju fun eko onipokeji ni (International Islamic University) ni ilu Malasia. O je eni ti o ni igbiyanju ni ori ipepe si oju ona Olohun ni ilana sunna.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 5

    Won je akekojade ni ile eko giga Imam University ni ilu Riyadh, won si je oluko ni ile eko giga Al-hikmah University. Won je oludari Al-imaam Ahmad Islamic Centre, won si ni igbiyanju lori ise ipepe si oju ona Olohun ni ilana Sunna.

  • Yoruba

    Onkọwe, Eni ti o se ogbifo, Onka awon ohun amulo : 54

    Akekojade ni ile iwe giga Islamic University ni ilu Madina. Bakannaa ni Sheikh keko ni ile iwe giga yi ti won si gba oye Dokita ninu imo Adiokan esin (Akiida). Won je okan Pataki ninu awon onimimo ni oju ona Al-sunna ni ile Yoruba ati ilu Nigeria lapapo.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 1

    O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o tun ko eko onipokeji ni ile eko giga University of Ilorin. O je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni liana sunna, o si ni igbiyanju lori oro esin.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 10

    Won je okan ninu awon onimimo ni ilana sunna (Ahlus-sunna wal-jamaaha) ni ile Yoruba. Won wa imo ni odo awon alfaa ni ile Nigeria. Won si je alfaa agba ninu ijo sunna kan ti oruko re nje (The Muslim Congress). Won ni igbiyanju ti o po lori ipepe si oju ona Olohun ati itosona fun awon Musulumi.

  • Yoruba

    Eni ti o se atunyewo, Onkọwe, Eni ti o se ogbifo, Onka awon ohun amulo : 304

    O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ile Niger Republic, O si ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ni ilana Sunna.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 17

    Imran Abdul Majeed Ẹlẹha: O jẹ akẹkọjade ile iwe giga King Saud University ni ilu Riyadh, o si jẹ oludasilẹ Daaru Nai’m Islamic Society, Nigeria. O ni igbiyanju lori ipepe si oju ọna Ọlọhun ni ilana awọn oni Sunna.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 40

    Won je okan ninu awon Onimimo ni oju ona sunna (Ahlu-sunna wal-jamaaha) . Won je eni ti o ko eko nipa imo Sharia ni odo awon Aafa ni ilu Nigeria. Won si je okan ninu awon Janmaa sunna ti oruko re nje (Jamaahatu Tadhoomunul Muslimeen). Won ni igbiyanju ti o po lori ipepe si oju ona Olohun ati itosona awon Musulumi.

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 3

    O je Akekojade ni ile eko giga ni ilu Medina (Islamic University), o si tun ko eko bi a tise nkoni ni ile eko giga ni ilu Riyadh (King Saud University), lowolowo bayi o je olupepe si oju ona Olohun ati oluko ni ilu Eko.

  • Yoruba

    Orisun, Olutẹjade, Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 402

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 332

  • Yoruba

    Onkọwe, Onka awon ohun amulo : 39

    O je akekojade ni ile eko giga Al-imam University ni ilu Riyadh, o si je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. O tun je oludasile ati olori Jamiyyatul Idaaya ni adugbo Olambe ni ipinle Ogun. O ni igbiyanju ti o po ni oju ona Olohun ati ipepe si esin Islam.

Oju ewe : 2 - Lati : 1