Awọn isę Hajj
Pípèsè :
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Awọn ise Hajj: Aworan ti a ṣe ni ede Yoruba, ti Sheikh Dr. Haitham Sarhan pese re, o ṣe alaye gbogbo ohun ti alalaji nilo, ni ipele ipele, ati ni ọna ti o dara ati ṣoki, ti o ṣe apejuwe pẹlu awọn aworan ati awọn aami, ki a le se ise orayan nla yii gege bi Anabi Muhammad se se e, ki ike ati ola Olohun maa ba, Eniti o so pe: E gba awon ise Hajji yin lowo mi.
- 1
PDF 2.94 MB 2023-25-06
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: