• The Right Path Islamic Foundation "Onka awon ohun amulo : 12"

    Ọ̀rọ̀ ṣókí :O je ajo kan ti o nse amojuto titan esin ka ni ilana Sunna ni ile Yoruba ati ilu Nigeria ni apapo. Awon olupepe si oju ona Olohun ti won si je onimimo ni won da a sile.