Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ

Ọ̀rọ̀ ṣókí

1- Awọn akori ọrọ ti o jẹyọ ni abala yii ni wọnyii:
(i).Itumọ sise Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ.
(ii). Alaye lori awọn ti wọn lodi si Sunna nibi ilana yii.
2- Alaye nipa ilana awọn ti won tẹle Sunna nibi orukọ Ọlọhun ati awọn iroyin Rẹ.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii