Awon Eko ti o nbe nibi Ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab

Oludanileko : Rafiu Adisa Bello

نبذة مختصرة

Alaye waye ninu ibanisoro yi nipa awon eko ti o nbe nibi ipepe Sheikh Muhammad ibn Abdul-wahab. Oniwaasi so nipa bi o se je wipe soki ohun ti ipepe Sheikh da le lori ni mimo Olohun ni okan soso ati dida oju ko O ni Oun nikan nibi awon ijosin.

التصانيف العلمية:

Irori re je wa logun