Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Idanilẹkọ yi da lori wipe idakeji ẹbọ sise ni sise Ọlọhun Allah ni aaso tabi gbigba A ni okan soso pẹlu ẹri Alukuraani ati ẹgbawa hadisi.
Alaye tẹsiwaju nipa itumọ ẹbọ sise pẹlu awọn ọna ti ẹbọ sise pin si.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii