Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a)
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye.
2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ Ọlọhun ni Anọbi Isa bi?
3- Idanilẹkọ ni agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere wọnyii:
- Njẹ Anọbi Isa ku ati wipe nibo ni o ku si?
- Njẹ Anọbi Isa npada bọ wa si aye, ati wipe igba wo ni?
- Ki ni yoo sẹlẹ ni asiko pipadabọọ rẹ?
- Awọn ẹri ti o da lori pipadabọọ rẹ.
- 1
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a)- 1
MP3 25.8 MB 2019-05-02
- 2
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a)- 2
MP3 26.1 MB 2019-05-02
- 3
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a)- 3
MP3 25.2 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: