Description

1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye.
2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ Ọlọhun ni Anọbi Isa bi?
3- Idanilẹkọ ni agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere wọnyii:
- Njẹ Anọbi Isa ku ati wipe nibo ni o ku si?
- Njẹ Anọbi Isa npada bọ wa si aye, ati wipe igba wo ni?
- Ki ni yoo sẹlẹ ni asiko pipadabọọ rẹ?
- Awọn ẹri ti o da lori pipadabọọ rẹ.

Irori re je wa logun