Atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun Allah

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Koko ibanisọrọ yii ni: (i) Itumọ atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun (ii) Awọn ọna ti a ngba se atẹgun lati wa oore ni ọdọ Ọlọhun. (iii) Awọn gbolohun ti o lẹtọ ti Musulumi fi le se atẹgun lọ si ọdọ Ọlọhun.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii