Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ
Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri.
2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa ti o maa nmu Musulumi bẹ ninu Ina fun igba diẹ.
- 1
Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - 1
MP3 26.2 MB 2019-05-02
- 2
Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - 2
MP3 26.1 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: