Awọn Aisedeede ti o maa nsẹlẹ pupọ lori Irun

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Pataki irun kiki ati wipe ohun ni akọkọ ohun ti Musulumi yoo se isiro rẹ ni ọjọ ajinde.
Diẹ ninu awọn aisedeede naa gẹgẹ bii: aifarabalẹ, wiwo ọtun wosi lori irun ati bẹẹbẹẹ lọ.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii