-
Dhikrullah Shafihi "Onka awon ohun amulo : 10"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :Won je okan ninu awon onimimo ni ilana sunna (Ahlus-sunna wal-jamaaha) ni ile Yoruba. Won wa imo ni odo awon alfaa ni ile Nigeria. Won si je alfaa agba ninu ijo sunna kan ti oruko re nje (The Muslim Congress). Won ni igbiyanju ti o po lori ipepe si oju ona Olohun ati itosona fun awon Musulumi.