-
Abdul-waahid Abdul-hameed "Onka awon ohun amulo : 1"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina. Won si te siwaju fun eko onipogiga (Masters) ni ilu Nigeria. Won je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. Won si je eni ti o ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun.