-
Imran Abdul Majeed Ẹlẹha "Onka awon ohun amulo : 17"
Ọ̀rọ̀ ṣókí :Imran Abdul Majeed Ẹlẹha: O jẹ akẹkọjade ile iwe giga King Saud University ni ilu Riyadh, o si jẹ oludasilẹ Daaru Nai’m Islamic Society, Nigeria. O ni igbiyanju lori ipepe si oju ọna Ọlọhun ni ilana awọn oni Sunna.