Islamhouse.com

  • Android
  • iOS
  • Windows
  • API
  • HTML
  • QuranEnc.com
  • HadeethEnc.com
Iru
    • Ojú ìwé ipilẹ
    • Gbogbo awon ede
    • Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀
    • Mo nipa Islam
    • Gbogbo àwọn iṣẹ́
      • Gbogbo àwọn iṣẹ́
      • Iwe
      • Àwọn Àpilẹ̀kọ
      • Àwọn ìdáhùn sí àwọn ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn
      • Fonran aworan
      • Fonran ohun
      • Àwọn àwòrán
      • Awọn ikanni ti àwọn èèyàn fẹ́ràn julọ
      • Àwọn ohun èlò
    • Lati gba Islam bayii
    • Àwọn nǹkan ti a n ṣe
    • Alekun
      • Awon eeyan jankan jankan
      • Àwọn ipilẹ ti a ti mú nǹkan
      • Windows version
      • Android version
      • iPhone version
      • QuranEnc.com
      • HadeethEnc.com
    YOYoruba
    معلومات المواد باللغة العربية

    Mo nipa Islam

    Onka awon ohun amulo: 9

    1. Ojú ìwé ipilẹ
    2. Interface Language : Yoruba
    3. Language of the content : Yoruba
    4. Mo nipa Islam
    • Fonran ohun
      • Iwe
      • Àwọn Àpilẹ̀kọ
      • Àwọn ìdáhùn sí àwọn ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn
      • Fonran aworan
      • Fonran ohun
    • Yoruba
      • Akane
      • Awọn Pọtuga
      • Awọn ara Baloshia
      • Awọn ara Bangali
      • Awọn ara Bọgeria
      • Awọn ara China
      • Awọn ara Faranse
      • Awọn ara Ghamokia
      • Awọn ara Giriki
      • Awọn ara Kannadan
      • Awọn ara Kazakh
      • Awọn ara Koria
      • Awọn ara Kurdi
      • Awọn ara Madagasika
      • Awọn ara Nẹpal
      • Awọn ara Pasia
      • Awọn ara Romania
      • Awọn ara Rọọsia
      • Awọn ara Sawahili
      • Awọn ara Sinhale
      • Awọn ara Somalia
      • Awọn ara Uganda
      • Awọn ara Vietnam
      • Awọn ara ilẹ Larubawa
      • Aymara
      • Bambara
      • Bosnia
      • Ede Alibania
      • Ede Amariki
      • Ede Ayigori
      • Ede Indonesia
      • Ede Italia
      • Ede Jamani
      • Ede Oromọ
      • Ede Oyinbo
      • Ede Siipaniisi
      • Ede Tamazigi
      • Ede Urudu
      • Ede Usibẹẹki
      • Fula
      • Hausa
      • Hindi
      • Igbo
      • Lao
      • Malayalam
      • Moore
      • Pashto
      • Quechua
      • Sango
      • Saraguli
      • Tajik
      • Tamasheq
      • Telugu
      • Thai
      • Ti èdè Afar
      • Ti èdè Tagalog
      • Ti ìlú Serbia
      • Tigrinya
      • Turkey
      • Turkmani
      • Wolof
      • Yoruba
      • Èdè Kurmanji
    • Yoruba

      Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam

      17 / 2 / 1436 , 10/12/2014

      Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde. 2- Alaye waye ni apa yii lori: (1) Awọn agbegbe yoku ti o ti yẹ ki eniyan ti maa se aanu. (2) Awọn anfaani ti o wa ninu aanu sise. (3) Sise daradara pẹlu awọn ẹranko naa wa lara aanu sise.

    • Yoruba

      Die Ninu Awon Ewa Islam

      22 / 6 / 1435 , 23/4/2014

      Oludanileko : Hamid Yusuf Oludanileko : Abdul-jeleel Alagufon Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun. 2- Ninu awon Ewa esin Islam ti oniwaasi menu ba ninu apa keji yi ni bi Islam se je esin gbogbo abgaye, ti o tun je esin ti o pe perepere, bakannaa ti o si je esin ti o rorun julo.

    • Yoruba

      Itosona Lori Asigbo Esin

      22 / 5 / 1435 , 24/3/2014

      Oludanileko : Hamid Yusuf Oludanileko : Abdul-jeleel Alagufon Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      1- Ibanisoro yii da lori awon ona abayo si asigbo esin ti o gbaye kan laarin awon Musulumi. 2- Ibanisoro je afikun lori awon okunfa ati ona abayo si awon asigbo tabi aseju ninu esin.

    • Yoruba

      Idahun si Awon Iruju Kan nipa Esin Islam

      15 / 4 / 1435 , 16/2/2014

      Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      Eyi ni alaye oro lekunrere nipa asigbo ati ero buburu ti awon eniyan ni si awon musulumi ati Esin Islam, ti olubanisoro si tun se alaye awon iruju die nipa iko “Boko Haram”.

    • Yoruba

      Awọn Ohun ti o rọ mọ Sisọkalẹ Anabi Isa [ Ọla Ọlọhun ki o maa ba a ]

      17 / 7 / 1437 , 25/4/2016

      Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      Alaye lẹkunrẹrẹ nipa ohun ti o rọ mọ sisọkalẹ Anabi Isa [ Ọla Ọlọhun ki o maa ba a ].

    • Yoruba

      Igbagbọ si Awọn Ojisẹ Ọlọhun

      29 / 5 / 1437 , 9/3/2016

      Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      Ninu idanilẹkọ yii: (i) Itumọ nini igbagbọ si awọn Ojisẹ Ọlọhun pẹlu ẹri rẹ lati Shẹriah, (ii) Pataki awọn Ojisẹ Ọlọhun ati bukaata wa si wọn.

    • Yoruba

      Ibasepọ Musulumi pẹlu Ẹlẹsin miran

      10 / 4 / 1437 , 21/1/2016

      Oludanileko : Sharafuddeen Gbadebọ Raji Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      Alaye ni ẹkunrẹrẹ nipa awọn ojuse Musulumi si awọn ẹlomiran ti kii se musulumi.

    • Yoruba

      Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ

      15 / 3 / 1437 , 27/12/2015

      Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ. 2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ di Ọlọhun. 3- Ọrọ nipa isẹ ipepe anọbi Isa pẹlu isẹ ayanu rẹ, ati wipe Iru ẹlẹsin wo ni Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a].

    • Yoruba

      Ninu awọn Iwa Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]

      25 / 2 / 1437 , 8/12/2015

      Oludanileko : Abdur Rahman Muhammadul Awwal Sise atunyewo : Hamid Yusuf

      Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]

    Oju ewe : 1 - Lati : 1
    • 1
    • Igbeyin

    Important links

    • IslamHouse Reader
    • What Muslim Children Must Know
    • Tafsir Saadi
    • Riyadh Al-Salheen
    • Kan si wa

    Maa tele wa lori

    Darapọ mọ ìtòlẹ́sẹẹsẹ ti i-meeli

    © Ikanni ayelukara IslamHouse.com

    Choose language

      Maa tele wa lori

        Darapọ mọ ìtòlẹ́sẹẹsẹ ti i-meeli