Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -1

Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -1

Oludanileko : Sharafuddeen Gbadebọ Raji

Sise atunyewo: Hamid Yusuf

Ọ̀rọ̀ ṣókí

Khadijah jẹ ẹniti awọn ara ilu Mẹkkah gba pe o mọ ninu awọn obinrin ki ẹsin Islam too de, oun si ni ẹni akọkọ ti o kọkọ gba Islam.

Download
Ko idasọrọ si alamojuto oju ewe yii