Alaye Lori Awon Iruju ti o nbe fun Awon Eniyan Kan nipa Wiwa Ategun (At-tawassul)
Ọ̀rọ̀ ṣókí
Ibanisoro yi da lori alaye ni ekunrere lori awon iruju ti o nbe fun awon eniyan kan nipa awon ohun ti o leto ki Musulumi maa fi se ategun si odo Olohun ati awon nkan ti ko leto nigbati o ba npe Olohun.
- 1
Alaye Lori Awon Iruju ti o nbe fun Awon Eniyan Kan nipa Wiwa Ategun (At-tawassul)
MP3 12.6 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: