Esin Islam ati Oro nipa Eto Oselu Tiwa- ntiwa (Demokiresi)
Oludanileko : Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Eleyi ni oro nipa ohun ti o je ojuse Musulumi nibi ibo didi ati idajo Islam lori kikopa ninu idibo.
2- Itesiwaju nipa ohun ti Islam so lori eto oselu tiwa- ntiwa (Demokiresi), olubanisoro menu ba idajo esin lori dida egbe oselu sile ati kikopa ninu re, o si tun so nipa ojuse eniti o ba fe gbegba fun ipo oselu.
- 1
Esin Islam ati Oro nipa Eto Oselu Tiwa- ntiwa (Demokiresi)- 01
MP3 10.9 MB 2019-05-02
- 2
Esin Islam ati Oro nipa Eto Oselu Tiwa- ntiwa (Demokiresi)- 02
MP3 14.1 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: