Alaye nipa Irun Onirin-ajo ati Alaare ninu tira Buluugul-maraam
Oludanileko : Sharafuddeen Gbadebọ Raji
Sise atunyewo: Hamid Yusuf
Ọ̀rọ̀ ṣókí
1- Idanileko yi soro nipa bi arinrin-ajo ati alaare yoo se maa ki irun won laini fi wole tabi lo o lara tayo asiko re.
2- Kiki irun rakah merin ni meji ni ori irinajo ati ki alaare fi aawe sile ninu osu Ramadan ki o si gba a pada nigbati ara re ba ya gbogbo eleyi je irorun ti Olohun se fun awa Musulumi ti O si fe ki a maa je anfaani re nitoripe irorun ni Olohun fe fun wa ninu Esin Islam.
3- Alaye ni ekunrere lori awon idajo irun onirin-ajo, igba ti yoo maa bere si din irun re ku ati asiko ti yoo fi din irun ku, bakannaa oro waye lori awon isesi onirin-ajo nipa awon irun ti yoo maa pe ati eyi ti yoo maa din ku.
4- Oro waye ninu apa kerin yi lori idajo kiki irun meji papo fun onirin-ajo ati awon ohun ti o le se okunfa kiki irun papo bakannaa fun eni ti kii se onirin-ajo.
5- Alaye nipa awon iruju ti o maa n waye lori irun arinrin-ajo ati irun alaare, bakannaa nipa pataki iranti Olohun ni gbogbo igba.
- 1
Alaye nipa Irun Onirin-ajo ati Alaare ninu tira Buluugul-maraam -1
MP3 16.8 MB 2019-05-02
- 2
Alaye nipa Irun Onirin-ajo ati Alaare ninu tira Buluugul-maraam -2
MP3 14.9 MB 2019-05-02
- 3
Alaye nipa Irun Onirin-ajo ati Alaare ninu tira Buluugul-maraam -3
MP3 16.9 MB 2019-05-02
- 4
Alaye nipa Irun Onirin-ajo ati Alaare ninu tira Buluugul-maraam -4
MP3 17.3 MB 2019-05-02
Àwọn ìsọ̀rí ti ìmọ̀: